Wednesday, 2 September 2020

Kay Wonder – “My father’s Love” | Feat. Beejay Sax | @Kay_Wonder1, @beejaysaxbolaji | Renowned worship/ Praise leaders Kay Wonder releases another soul lifting song alongside with the fast growing Nigerian Saxophonist BeeJay Sax titled “My Father’s Love” is a song that talks about the boundless, endless, undying love of God towards us and the beautiful uncountable blessings we enjoy as His children. The song is a song of gratitude to God as our anchor rests entirely on the assurance of His love towards us. Download, enjoy and share. DOWNLOAD AUDIO Lyrics My Father’s Love {Kaywonder feat BeejaySax} Verse 1 I have a father that cares for me His Love is so boundless His Love is so endless He will never fail . I have a Father that cares for me His Love is so boundless His Love is so endless He will never fail . I will follow you until the very end even if I fall You will never leave me Just like a prodigal son You still welcome me back again . Chorus . Ese eyi tan o jo aye loju Eyin saa ni father mi gbogbo aye ti mo pe e o loroogun Eyin ni baba to mo iyi omo . {BeejaySax}… Solo Res…. Lalalalalalalala Chorus . Ese eyi tan o jo aye loju Eyin saa ni father wa gbogbo aye ti mo pe e o loroogun Eyin ni baba to mo iyi omo/2ce . Verse 2 . Call…. Awa ni baba kan Res…. Baba kan Call…. Baba to iyi Omo Call…. Baba to nke wa bi eyin Call…. O pon wa bi omo Call…. He’s the Father of the fatherless Call…. Helper of the helpless Call…. Hope of years to come Call…. Helper in the time of need Call…. Treasure of my heart / My Shield Call…. Baba ayeraye loruko Yin o Call…. Baba alanu . Chorus . E seyi tan, o jo aye loju Eyin saa ni father wa Gbogbo aye ti mo pe e o loroogun Eyin ni baba to mo iyi omo . Verse 3 . E mo iyi mi Jesu Emo iyi mi E mo iyi emi omo yin “Kaywonder” Jesu E mo iyi mi Eyin le o je a Jalule nigbati mimi aye ba mi wa, Abiyamo Orun ese ti e pon wa bi omo . Jesu E mo iyi mi Babaa mi E mo iyi mi atobajaye Emo iyi omo Yagboyaaju E mo iyi omo yin Eyin le o je a Jalule nigbati iji aye ba mi wa, Abiyamo Orun ese ti e pon wa bi omo . Chorus E seyi tan o no aye loju (Ise igbala te se fun wa) eyin saa ni father wa gbogbo aye ti mo pe e o loroogun eyin ni baba to mo iyi omo . Coda… . Call…. Eyin ni baba olutoju wa . Res…. Baba Baba E ma see eyin baba to mo iyi omo, . {SanmiConga} Percussions…… . {Epeeloruko} {All echo} . Baba Baba Eku ise Lori oro aye mi Eyin gan gan Lagba otipe tipe t’e ti nba wabo Gbegiiiiiiiiiiii…..{Echo of rejoicing} . {Holy Ghost chanting} Agboo mati Baaba mi agbalagba olore akanse oofi oope damu ologbon ooso ologbon di oope Eyin ni orisun Agbongbe ibukun Afi weeree Pari ise Afi aikanju ko ni yo ninu ewu idamu Oba mi akiki tan ede eniti ko ba mo Oba lo n foba sere Oba to mu ogun sinakerubu sun oorun ejika Akooni ninu Awon Akooni okunrin Eyin ni babami. . Call…. Eyin baba Olutoju mi o Res….Baba, Baba, E ma se eyin baba to mo iyi omo . .Baba o eyin ni baba o All…. Baba ooo Eyin ni baba o Baba eyin ni baba o The post Kay Wonder – “My father’s Love” | Feat. Beejay Sax | @Kay_Wonder1, @beejaysaxbolaji | appeared first on Gospel Centric. https://ift.tt/2DjRHwC

Renowned worship/ Praise leaders Kay Wonder releases another soul lifting song alongside with the fast growing Nigerian Saxophonist BeeJay Sax titled “My Father’s Love” is a song that talks about the boundless, endless, undying love of God towards us and the beautiful uncountable blessings we enjoy as His children.

The song is a song of gratitude to God as our anchor rests entirely on the assurance of His love towards us.

Download, enjoy and share.

DOWNLOAD AUDIO

Lyrics My Father’s Love {Kaywonder feat BeejaySax}

Verse 1

I have a father that cares for me
His Love is so boundless
His Love is so endless
He will never fail
.
I have a Father that cares for me
His Love is so boundless
His Love is so endless
He will never fail
.
I will follow you
until the very end
even if I fall
You will never leave me
Just like a prodigal son
You still welcome me back again
.
Chorus
.
Ese eyi tan o jo aye loju
Eyin saa ni father mi
gbogbo aye ti mo
pe e o loroogun
Eyin ni baba
to mo iyi omo
.
{BeejaySax}… Solo
Res…. Lalalalalalalala

Chorus
.
Ese eyi tan o jo aye loju
Eyin saa ni father wa
gbogbo aye ti mo
pe e o loroogun
Eyin ni baba
to mo iyi omo/2ce
.
Verse 2
.
Call…. Awa ni baba kan
Res…. Baba kan
Call…. Baba to iyi Omo
Call…. Baba to nke wa bi eyin
Call…. O pon wa bi omo
Call…. He’s the Father of the fatherless
Call…. Helper of the helpless
Call…. Hope of years to come
Call…. Helper in the time of need
Call…. Treasure of my heart / My Shield
Call…. Baba ayeraye loruko Yin o
Call…. Baba alanu
.
Chorus
.
E seyi tan,
o jo aye loju
Eyin saa ni father wa
Gbogbo aye ti mo pe e o loroogun
Eyin ni baba to mo iyi omo
.
Verse 3
.
E mo iyi mi
Jesu Emo iyi mi
E mo iyi emi omo yin “Kaywonder”
Jesu E mo iyi mi
Eyin le o je a Jalule
nigbati mimi aye ba mi wa,
Abiyamo Orun
ese ti e pon wa bi omo
.
Jesu
E mo iyi mi
Babaa mi
E mo iyi mi
atobajaye
Emo iyi omo
Yagboyaaju
E mo iyi omo yin
Eyin le o je a Jalule
nigbati iji aye ba mi wa,
Abiyamo Orun
ese ti e pon wa bi omo
.
Chorus
E seyi tan
o no aye loju
(Ise igbala te se fun wa)
eyin saa ni father wa
gbogbo aye ti mo
pe e o loroogun
eyin ni baba
to mo iyi omo
.
Coda…
.
Call….
Eyin ni baba olutoju wa
.
Res….
Baba Baba E ma see eyin baba to mo iyi omo,
.
{SanmiConga} Percussions……
.
{Epeeloruko}
{All echo}
.
Baba Baba
Eku ise
Lori oro aye mi
Eyin gan gan Lagba
otipe tipe t’e ti nba wabo
Gbegiiiiiiiiiiii…..{Echo of rejoicing}
.
{Holy Ghost chanting}
Agboo mati
Baaba mi agbalagba
olore akanse
oofi oope damu ologbon
ooso ologbon di oope
Eyin ni orisun
Agbongbe ibukun
Afi weeree Pari ise
Afi aikanju ko ni yo
ninu ewu idamu
Oba mi akiki tan ede
eniti ko ba mo Oba
lo n foba sere
Oba to mu ogun sinakerubu sun oorun ejika
Akooni ninu Awon Akooni okunrin
Eyin ni babami.
.
Call…. Eyin baba Olutoju mi o
Res….Baba, Baba, E ma se eyin baba to mo iyi omo
.
.Baba o eyin ni baba o
All….
Baba ooo
Eyin ni baba o
Baba eyin ni baba o

The post Kay Wonder – “My father’s Love” | Feat. Beejay Sax | @Kay_Wonder1, @beejaysaxbolaji | appeared first on Gospel Centric.




FACO
https://ift.tt/2lfRwHW

No comments:

Post a Comment